Saamu 73:17
Psalms 73:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
títí mo fi wọ ibi mímọ́ Ọlọ́run; nígbà náà ni òye ìgbẹ̀yìn wọn yé mi.
Psalms 73:17 in English
Psalms 73:17 · Berean Standard Bible
until I entered God’s sanctuary; then I discerned their end.
Context
15Bí mo bá wí pé, “Èmi ó wí báyìí,”
èmi ó ṣẹ̀ sí ìran àwọn ọmọ rẹ̀. 16Nígbà tí mo gbìyànjú láti mọ èyí,
Ó jẹ́ ìnilára fún mi, 17títí mo fi wọ ibi mímọ́ Ọlọ́run;
nígbà náà ni òye ìgbẹ̀yìn wọn yé mi. 18Lóòtítọ́ ìwọ gbé wọn lórí ilẹ̀ yíyọ́
ìwọ jù wọ́n sílẹ̀ sínú ìparun. 19Báwo ní a ti mú wọn lọ sínú ìdahoro yìí
bí ẹni pé ní ìṣẹ́jú kan!
Ìbẹ̀rù ni a fi ń run wọ́n pátápátá!
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.