Native Bible

Psalms 73:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí mo gbìyànjú láti mọ èyí, Ó jẹ́ ìnilára fún mi,

Psalms 73:16 in English

Psalms 73:16 · Berean Standard Bible

When I tried to understand all this, it was troublesome in my sight

Context

14Ní gbogbo ọjọ́ ni a ń yọ mí lẹ́nu; a sì ń jẹ mí ní yà ní gbogbo òwúrọ̀. 15Bí mo bá wí pé, “Èmi ó wí báyìí,” èmi ó ṣẹ̀ sí ìran àwọn ọmọ rẹ̀. 16Nígbà tí mo gbìyànjú láti mọ èyí, Ó jẹ́ ìnilára fún mi, 17títí mo fi wọ ibi mímọ́ Ọlọ́run; nígbà náà ni òye ìgbẹ̀yìn wọn yé mi. 18Lóòtítọ́ ìwọ gbé wọn lórí ilẹ̀ yíyọ́ ìwọ jù wọ́n sílẹ̀ sínú ìparun.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.