Saamu 69:21
Psalms 69:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n fi òróró fún mi pẹ̀lú ohun jíjẹ mi, àti ní òùngbẹ mi, wọ́n fi ọtí kíkan fún mi.
Psalms 69:21 in English
Psalms 69:21 · Berean Standard Bible
They poisoned my food with gall and gave me vinegar to quench my thirst.
Context
19Ìwọ ti mọ ẹ̀gàn mi, ìtìjú mi àti àìlọ́lá;
gbogbo àwọn ọ̀tá mi wà níwájú rẹ. 20Ẹ̀gàn ba ọkàn mi jẹ́,
wọ́n fi mí sílẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́;
mo ń wá aláàánú, ṣùgbọ́n kò sí,
mo ń wá olùtùnú, ṣùgbọ́n n kò rí ẹnìkankan. 21Wọ́n fi òróró fún mi pẹ̀lú ohun jíjẹ mi,
àti ní òùngbẹ mi, wọ́n fi ọtí kíkan fún mi. 22Jẹ́ kí tábìlì wọn kí ó di ìkẹ́kùn
ní iwájú wọn, kí ó sì di okùn dídẹ
fún àwọn tó wà ní àlàáfíà. 23Kí ojú wọn kì í ó ṣókùnkùn, kí wọn má ṣe ríran,
kí ẹ̀yin wọn di títẹ̀ títí láé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.