Saamu 69:19
Psalms 69:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ ti mọ ẹ̀gàn mi, ìtìjú mi àti àìlọ́lá; gbogbo àwọn ọ̀tá mi wà níwájú rẹ.
Psalms 69:19 in English
Psalms 69:19 · Berean Standard Bible
You know my reproach, my shame and disgrace. All my adversaries are before You.
Context
17Má ṣe pa ojú rẹ mọ́ fún ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ:
yára dá mi lóhùn, nítorí mo wà nínú ìpọ́njú. 18Súnmọ́ tòsí kí o sì gbà mí là;
rà mí padà nítorí àwọn ọ̀tá mi. 19Ìwọ ti mọ ẹ̀gàn mi, ìtìjú mi àti àìlọ́lá;
gbogbo àwọn ọ̀tá mi wà níwájú rẹ. 20Ẹ̀gàn ba ọkàn mi jẹ́,
wọ́n fi mí sílẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́;
mo ń wá aláàánú, ṣùgbọ́n kò sí,
mo ń wá olùtùnú, ṣùgbọ́n n kò rí ẹnìkankan. 21Wọ́n fi òróró fún mi pẹ̀lú ohun jíjẹ mi,
àti ní òùngbẹ mi, wọ́n fi ọtí kíkan fún mi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.