Native Bible

Psalms 69:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Gbà mí, Ọlọ́run, nítorí omi ti kún dé ọrùn mi.

Psalms 69:1 in English

Psalms 69:1 · Berean Standard Bible

Save me, O God, for the waters are up to my neck.

Context

1Gbà mí, Ọlọ́run, nítorí omi ti kún dé ọrùn mi. 2Mo ń rì nínú irà jíjìn, níbi tí kò sí ibi ìfẹsẹ̀lé. Mo ti wá sínú omi jíjìn; ìkún omi bò mí mọ́lẹ̀. 3Agara dá mi, mo ń pè fún ìrànlọ́wọ́; ọ̀fun mí gbẹ, ojú mi ṣú, nígbà tí èmi dúró de Ọlọ́run mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.