Saamu 68:26
Psalms 68:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹ fi ìyìn fún Olúwa ní ẹgbẹgbẹ́; àní fún Olúwa ẹ̀yin tí ó ti orísun Israẹli wá.
Psalms 68:26 in English
Psalms 68:26 · Berean Standard Bible
Bless God in the great congregation; bless the LORD from the fountain of Israel.
Context
24Wọ́n ti rí ìrìn rẹ, Ọlọ́run,
ìrìn Ọlọ́run mi àti ọba mi ní ibi mímọ́ rẹ̀. 25Àwọn akọrin wà ní iwájú, àwọn olórin wà lẹ́yìn;
àwọn ọmọbìnrin tí ń lu ṣaworo sì wà pẹ̀lú wọn. 26Ẹ fi ìyìn fún Olúwa ní ẹgbẹgbẹ́;
àní fún Olúwa ẹ̀yin tí ó ti orísun Israẹli wá. 27Níbẹ̀ ní ẹ̀yà kékeré Benjamini wà, tí ó ń darí wọn,
níbẹ̀ ni àwọn ọmọ-aládé Juda,
níbẹ̀ ni àwọn ọmọ-aládé Sebuluni àti tí Naftali. 28Pàṣẹ agbára rẹ, Ọlọ́run;
fi agbára rẹ hàn wá, Ọlọ́run, gẹ́gẹ́ bí ìwọ ti ṣe ní ìṣáájú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.