Saamu 68:24
Psalms 68:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n ti rí ìrìn rẹ, Ọlọ́run, ìrìn Ọlọ́run mi àti ọba mi ní ibi mímọ́ rẹ̀.
Psalms 68:24 in English
Psalms 68:24 · Berean Standard Bible
They have seen Your procession, O God— the march of my God and King into the sanctuary.
Context
22Olúwa wí pé, “Èmi ó mú wọn wá láti Baṣani;
èmi ó mú wọn wá láti ibú omi Òkun, 23kí ẹsẹ̀ rẹ kí ó le pọ́n ní inú ẹ̀jẹ̀ àwọn ọ̀tá rẹ,
àti ahọ́n àwọn ajá rẹ ní ìpín tiwọn lára àwọn ọ̀tá rẹ.” 24Wọ́n ti rí ìrìn rẹ, Ọlọ́run,
ìrìn Ọlọ́run mi àti ọba mi ní ibi mímọ́ rẹ̀. 25Àwọn akọrin wà ní iwájú, àwọn olórin wà lẹ́yìn;
àwọn ọmọbìnrin tí ń lu ṣaworo sì wà pẹ̀lú wọn. 26Ẹ fi ìyìn fún Olúwa ní ẹgbẹgbẹ́;
àní fún Olúwa ẹ̀yin tí ó ti orísun Israẹli wá.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.