Saamu 37:26
Psalms 37:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Aláàánú ni òun nígbà gbogbo a máa yá ni; a sì máa bùsi i fún ni.
Psalms 37:26 in English
Psalms 37:26 · Berean Standard Bible
They are ever generous and quick to lend, and their children are a blessing.
Context
24bí ó tilẹ̀ ṣubú a kì yóò ta á nù pátápátá,
nítorí tí Olúwa di ọwọ́ rẹ̀ mú. 25Èmi ti wà ni èwe, báyìí èmi sì dàgbà;
síbẹ̀ èmi kò ì tí ì ri kí a kọ olódodo sílẹ̀,
tàbí kí irú-ọmọ rẹ̀ máa ṣagbe oúnjẹ. 26Aláàánú ni òun nígbà gbogbo a máa yá ni;
a sì máa bùsi i fún ni. 27Lọ kúrò nínú ibi, kí o sì máa ṣe rere;
nígbà náà ni ìwọ yóò gbé ní ilẹ̀ náà títí láéláé. 28Nítorí pé Olúwa fẹ́ràn ìdájọ́ òtítọ́,
kò sì kọ àwọn ènìyàn mímọ́ rẹ̀ sílẹ̀.
Àwọn olódodo ni a ó pamọ́ títí ayérayé,
ṣùgbọ́n àwọn ọmọ ènìyàn búburú ni a ó ké kúrò.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.