Saamu 139:22
Psalms 139:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi kórìíra wọn ní àkótán; èmi kà wọ́n sí ọ̀tá mi.
Psalms 139:22 in English
Psalms 139:22 · Berean Standard Bible
I hate them with perfect hatred; I count them as my enemies.
Context
20Ẹni tí ń fi inú búburú sọ̀rọ̀ sí ọ,
àwọn ọ̀tá rẹ ń pe orúkọ rẹ ní asán! 21Olúwa, ǹjẹ́ èmi kò kórìíra àwọn tó kórìíra rẹ?
Ǹjẹ́ inú mi kò a sì bàjẹ́ sí àwọn tí ó dìde sí ọ? 22Èmi kórìíra wọn ní àkótán;
èmi kà wọ́n sí ọ̀tá mi. 23Ọlọ́run, wádìí mi, kí o sì mọ ọkàn mí;
dán mi wò, kí o sì mọ ìrò inú mi. 24Kí ó sì wò ó bí ipa ọ̀nà búburú
kan bá wà nínú mi kí ó sì
fi ẹsẹ̀ mi lé ọ̀nà àìnípẹ̀kun.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.