Native Bible

Psalms 139:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọlọ́run, wádìí mi, kí o sì mọ ọkàn mí; dán mi wò, kí o sì mọ ìrò inú mi.

Psalms 139:23 in English

Psalms 139:23 · Berean Standard Bible

Search me, O God, and know my heart; test me and know my concerns.

Context

21Olúwa, ǹjẹ́ èmi kò kórìíra àwọn tó kórìíra rẹ? Ǹjẹ́ inú mi kò a sì bàjẹ́ sí àwọn tí ó dìde sí ọ? 22Èmi kórìíra wọn ní àkótán; èmi kà wọ́n sí ọ̀tá mi. 23Ọlọ́run, wádìí mi, kí o sì mọ ọkàn mí; dán mi wò, kí o sì mọ ìrò inú mi. 24Kí ó sì wò ó bí ipa ọ̀nà búburú kan bá wà nínú mi kí ó sì fi ẹsẹ̀ mi lé ọ̀nà àìnípẹ̀kun.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.