Native Bible

Psalms 119:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọkàn mi pòruurù pẹ̀lú ìfojúsọ́nà nítorí òfin rẹ nígbà gbogbo.

Psalms 119:20 in English

Psalms 119:20 · Berean Standard Bible

My soul is consumed with longing for Your judgments at all times.

Context

18La ojú mi kí èmi lè ríran rí ohun ìyanu tí ó wà nínú òfin rẹ. 19Àlejò ní èmi jẹ́ láyé, má ṣe pa àṣẹ rẹ mọ́ fún mi. 20Ọkàn mi pòruurù pẹ̀lú ìfojúsọ́nà nítorí òfin rẹ nígbà gbogbo. 21Ìwọ fi àwọn agbéraga bú, àwọn tí a fi gégùn ún tí ó ṣìnà kúrò nínú àṣẹ rẹ. 22Mú ẹ̀gàn àti àbùkù kúrò lára mi, nítorí èmi pa òfin rẹ mọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.