Saamu 119:19
Psalms 119:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àlejò ní èmi jẹ́ láyé, má ṣe pa àṣẹ rẹ mọ́ fún mi.
Psalms 119:19 in English
Psalms 119:19 · Berean Standard Bible
I am a stranger on the earth; do not hide Your commandments from me.
Context
17Ṣe rere sí ìránṣẹ́ rẹ, èmi yóò sì wà láààyè;
èmi yóò ṣe ìgbọ́ràn sí ọ̀rọ̀ rẹ. 18La ojú mi kí èmi lè ríran rí
ohun ìyanu tí ó wà nínú òfin rẹ. 19Àlejò ní èmi jẹ́ láyé,
má ṣe pa àṣẹ rẹ mọ́ fún mi. 20Ọkàn mi pòruurù pẹ̀lú ìfojúsọ́nà
nítorí òfin rẹ nígbà gbogbo. 21Ìwọ fi àwọn agbéraga bú, àwọn tí a fi gégùn ún
tí ó ṣìnà kúrò nínú àṣẹ rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.