Saamu 119:18
Psalms 119:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
La ojú mi kí èmi lè ríran rí ohun ìyanu tí ó wà nínú òfin rẹ.
Psalms 119:18 in English
Psalms 119:18 · Berean Standard Bible
Open my eyes that I may see wondrous things from Your law.
Context
16Inú mi dùn sí àṣẹ rẹ;
èmi kì yóò gbàgbé ọ̀nà rẹ. 17Ṣe rere sí ìránṣẹ́ rẹ, èmi yóò sì wà láààyè;
èmi yóò ṣe ìgbọ́ràn sí ọ̀rọ̀ rẹ. 18La ojú mi kí èmi lè ríran rí
ohun ìyanu tí ó wà nínú òfin rẹ. 19Àlejò ní èmi jẹ́ láyé,
má ṣe pa àṣẹ rẹ mọ́ fún mi. 20Ọkàn mi pòruurù pẹ̀lú ìfojúsọ́nà
nítorí òfin rẹ nígbà gbogbo.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.