Native Bible

Psalms 119:146 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èmi kígbe pè ọ́; gbà mí èmi yóò sì pa òfin rẹ mọ́.

Psalms 119:146 in English

Psalms 119:146 · Berean Standard Bible

I call to You; save me, that I may keep Your testimonies.

Context

144Òfin rẹ jẹ́ òtítọ́ láé; fún mi ní òye kí èmi lè yè. 145Èmi kígbe pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi: dá mi lóhùn Olúwa, èmi yóò sì gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ. 146Èmi kígbe pè ọ́; gbà mí èmi yóò sì pa òfin rẹ mọ́. 147Èmi dìde ṣáájú àfẹ̀mọ́júmọ́ èmi ké fún ìrànlọ́wọ́; èmi ti mú ìrètí mi sínú ọ̀rọ̀ rẹ. 148Ojú mi ṣáájú ìṣọ́ òru, nítorí kí èmi lè ṣe àṣàrò nínú ọ̀rọ̀ rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.