Native Bible

Psalms 119:144 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Òfin rẹ jẹ́ òtítọ́ láé; fún mi ní òye kí èmi lè yè.

Psalms 119:144 in English

Psalms 119:144 · Berean Standard Bible

Your testimonies are righteous forever. Give me understanding, that I may live.

Context

142Òdodo rẹ wà títí láé òtítọ́ ni òfin rẹ̀. 143Ìyọnu àti ìpọ́njú wá sórí mi, ṣùgbọ́n àṣẹ rẹ ni inú dídùn mi. 144Òfin rẹ jẹ́ òtítọ́ láé; fún mi ní òye kí èmi lè yè. 145Èmi kígbe pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi: dá mi lóhùn Olúwa, èmi yóò sì gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ. 146Èmi kígbe pè ọ́; gbà mí èmi yóò sì pa òfin rẹ mọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.