Native Bible

Psalms 119:145 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èmi kígbe pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi: dá mi lóhùn Olúwa, èmi yóò sì gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ.

Psalms 119:145 in English

Psalms 119:145 · Berean Standard Bible

I call with all my heart; answer me, O LORD! I will obey Your statutes.

Context

143Ìyọnu àti ìpọ́njú wá sórí mi, ṣùgbọ́n àṣẹ rẹ ni inú dídùn mi. 144Òfin rẹ jẹ́ òtítọ́ láé; fún mi ní òye kí èmi lè yè. 145Èmi kígbe pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi: dá mi lóhùn Olúwa, èmi yóò sì gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ. 146Èmi kígbe pè ọ́; gbà mí èmi yóò sì pa òfin rẹ mọ́. 147Èmi dìde ṣáájú àfẹ̀mọ́júmọ́ èmi ké fún ìrànlọ́wọ́; èmi ti mú ìrètí mi sínú ọ̀rọ̀ rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.