Saamu 119:143
Psalms 119:143 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìyọnu àti ìpọ́njú wá sórí mi, ṣùgbọ́n àṣẹ rẹ ni inú dídùn mi.
Psalms 119:143 in English
Psalms 119:143 · Berean Standard Bible
Trouble and distress have found me, but Your commandments are my delight.
Context
141Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ àti ẹni ẹ̀gàn
èmi kò ni gbàgbé ẹ̀kọ́ rẹ. 142Òdodo rẹ wà títí láé
òtítọ́ ni òfin rẹ̀. 143Ìyọnu àti ìpọ́njú wá sórí mi,
ṣùgbọ́n àṣẹ rẹ ni inú dídùn mi. 144Òfin rẹ jẹ́ òtítọ́ láé;
fún mi ní òye kí èmi lè yè. 145Èmi kígbe pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi:
dá mi lóhùn Olúwa,
èmi yóò sì gbọ́rọ̀ sí àṣẹ rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.