Native Bible

Psalms 119:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èmi ń yọ̀ ní ọ̀nà ẹ̀rí rẹ, bí ènìyàn ṣe ń yọ̀ nínú ọláńlá.

Psalms 119:14 in English

Psalms 119:14 · Berean Standard Bible

I rejoice in the way of Your testimonies as much as in all riches.

Context

12Ìyìn ni fún Olúwa; kọ́ mi ní àṣẹ rẹ. 13Pẹ̀lú ètè mi èmi tún ṣírò gbogbo òfin tí ó wá láti ẹnu rẹ. 14Èmi ń yọ̀ ní ọ̀nà ẹ̀rí rẹ, bí ènìyàn ṣe ń yọ̀ nínú ọláńlá. 15Èmi ń ṣe àṣàrò nínú ìlànà rẹ èmi sì kíyèsi ọ̀nà rẹ. 16Inú mi dùn sí àṣẹ rẹ; èmi kì yóò gbàgbé ọ̀nà rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.