Native Bible

Psalms 119:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Pẹ̀lú ètè mi èmi tún ṣírò gbogbo òfin tí ó wá láti ẹnu rẹ.

Psalms 119:13 in English

Psalms 119:13 · Berean Standard Bible

With my lips I proclaim all the judgments of Your mouth.

Context

11Èmi ti pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́ ní ọkàn mi kí èmi má ba à ṣẹ̀ sí ọ. 12Ìyìn ni fún Olúwa; kọ́ mi ní àṣẹ rẹ. 13Pẹ̀lú ètè mi èmi tún ṣírò gbogbo òfin tí ó wá láti ẹnu rẹ. 14Èmi ń yọ̀ ní ọ̀nà ẹ̀rí rẹ, bí ènìyàn ṣe ń yọ̀ nínú ọláńlá. 15Èmi ń ṣe àṣàrò nínú ìlànà rẹ èmi sì kíyèsi ọ̀nà rẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.