Native Bible

Psalms 119:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìyìn ni fún Olúwa; kọ́ mi ní àṣẹ rẹ.

Psalms 119:12 in English

Psalms 119:12 · Berean Standard Bible

Blessed are You, O LORD; teach me Your statutes.

Context

10Èmi wá ọ pẹ̀lú gbogbo ọkàn mi má ṣe jẹ́ kí èmi yapa kúrò nínú àṣẹ rẹ. 11Èmi ti pa ọ̀rọ̀ rẹ mọ́ ní ọkàn mi kí èmi má ba à ṣẹ̀ sí ọ. 12Ìyìn ni fún Olúwa; kọ́ mi ní àṣẹ rẹ. 13Pẹ̀lú ètè mi èmi tún ṣírò gbogbo òfin tí ó wá láti ẹnu rẹ. 14Èmi ń yọ̀ ní ọ̀nà ẹ̀rí rẹ, bí ènìyàn ṣe ń yọ̀ nínú ọláńlá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.