Native Bible

Psalms 119:137 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olódodo ni ìwọ Olúwa ìdájọ́ rẹ sì dúró ṣinṣin.

Psalms 119:137 in English

Psalms 119:137 · Berean Standard Bible

Righteous are You, O LORD, and upright are Your judgments.

Context

135Jẹ́ kí ojú rẹ kí ó tàn sí ìránṣẹ́ rẹ lára kí ó sì kọ́ mi ní àṣẹ rẹ. 136Omijé sàn jáde ní ojú mi, nítorí wọn kò gba pé òfin rẹ̀ jẹ́ òtítọ́. 137Olódodo ni ìwọ Olúwa ìdájọ́ rẹ sì dúró ṣinṣin. 138Òfin ti ìwọ gbé kalẹ̀ jẹ́ òdodo: wọ́n yẹ ni ìgbẹ́kẹ̀lé. 139Ìtara mi ti pa mí run, nítorí àwọn ọ̀tá mi fi ojú fo ọ̀rọ̀ rẹ dá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.