Native Bible

Psalms 119:138 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Òfin ti ìwọ gbé kalẹ̀ jẹ́ òdodo: wọ́n yẹ ni ìgbẹ́kẹ̀lé.

Psalms 119:138 in English

Psalms 119:138 · Berean Standard Bible

The testimonies You have laid down are righteous and altogether faithful.

Context

136Omijé sàn jáde ní ojú mi, nítorí wọn kò gba pé òfin rẹ̀ jẹ́ òtítọ́. 137Olódodo ni ìwọ Olúwa ìdájọ́ rẹ sì dúró ṣinṣin. 138Òfin ti ìwọ gbé kalẹ̀ jẹ́ òdodo: wọ́n yẹ ni ìgbẹ́kẹ̀lé. 139Ìtara mi ti pa mí run, nítorí àwọn ọ̀tá mi fi ojú fo ọ̀rọ̀ rẹ dá. 140Wọ́n ti dán ìpinnu rẹ wò pátápátá ìránṣẹ́ rẹ sì fẹ́ràn wọ́n.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.