Saamu 119:129
Psalms 119:129 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Òfin rẹ̀ ìyanu ni: nítorí náà èmi gbà wọ́n gbọ́.
Psalms 119:129 in English
Psalms 119:129 · Berean Standard Bible
Wonderful are Your testimonies; therefore I obey them.
Context
127Nítorí èmi fẹ́ràn àṣẹ rẹ
ju wúrà, àní ju wúrà dídára lọ, 128nítorí èmi kíyèsi gbogbo ẹ̀kọ́ òtítọ́ rẹ̀,
èmi kórìíra gbogbo ipa ọ̀nà búburú. 129Òfin rẹ̀ ìyanu ni:
nítorí náà èmi gbà wọ́n gbọ́. 130Ìṣípayá ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú ìmọ́lẹ̀ wá;
ó fi òye fún àwọn òpè. 131Èmi ya ẹnu mi mo sì mí hẹlẹ,
nítorí èmi fojú ṣọ́nà sí àṣẹ rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.