Native Bible

Psalms 119:127 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nítorí èmi fẹ́ràn àṣẹ rẹ ju wúrà, àní ju wúrà dídára lọ,

Psalms 119:127 in English

Psalms 119:127 · Berean Standard Bible

Therefore I love Your commandments more than gold, even the purest gold.

Context

125Èmi ni ìránṣẹ́ rẹ; ẹ fún mi ní òye kí èmi lè ní òye òfin rẹ 126Ó tó àsìkò fún ọ láti ṣe iṣẹ́, Olúwa; nítorí òfin rẹ ti fọ́. 127Nítorí èmi fẹ́ràn àṣẹ rẹ ju wúrà, àní ju wúrà dídára lọ, 128nítorí èmi kíyèsi gbogbo ẹ̀kọ́ òtítọ́ rẹ̀, èmi kórìíra gbogbo ipa ọ̀nà búburú. 129Òfin rẹ̀ ìyanu ni: nítorí náà èmi gbà wọ́n gbọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.