Native Bible

Psalms 119:128 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

nítorí èmi kíyèsi gbogbo ẹ̀kọ́ òtítọ́ rẹ̀, èmi kórìíra gbogbo ipa ọ̀nà búburú.

Psalms 119:128 in English

Psalms 119:128 · Berean Standard Bible

Therefore I admire all Your precepts and hate every false way.

Context

126Ó tó àsìkò fún ọ láti ṣe iṣẹ́, Olúwa; nítorí òfin rẹ ti fọ́. 127Nítorí èmi fẹ́ràn àṣẹ rẹ ju wúrà, àní ju wúrà dídára lọ, 128nítorí èmi kíyèsi gbogbo ẹ̀kọ́ òtítọ́ rẹ̀, èmi kórìíra gbogbo ipa ọ̀nà búburú. 129Òfin rẹ̀ ìyanu ni: nítorí náà èmi gbà wọ́n gbọ́. 130Ìṣípayá ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú ìmọ́lẹ̀ wá; ó fi òye fún àwọn òpè.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.