Saamu 106:12
Psalms 106:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbà náà wọn gba ìpinnu rẹ gbọ́ wọ́n sì kọrin ìyìn rẹ.
Psalms 106:12 in English
Psalms 106:12 · Berean Standard Bible
Then they believed His promises and sang His praise.
Context
10O gbà wọ́n là kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn,
láti ọwọ́ ọ̀tá ni o ti gbà wọ́n. 11Omi ya lu àwọn ọ̀tá wọn;
bẹ́ẹ̀ ni kò sí èyí tí ó yè nínú wọn. 12Nígbà náà wọn gba ìpinnu rẹ gbọ́
wọ́n sì kọrin ìyìn rẹ. 13Ṣùgbọ́n wọn kò pẹ́ gbàgbé ohun tí o ṣe
wọn kò sí dúró gba ìmọ̀ràn rẹ. 14Nínú aginjù ni wọ́n tí ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́,
nínú aṣálẹ̀, wọ́n dán Ọlọ́run wò.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.