Saamu 106:11
Psalms 106:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Omi ya lu àwọn ọ̀tá wọn; bẹ́ẹ̀ ni kò sí èyí tí ó yè nínú wọn.
Psalms 106:11 in English
Psalms 106:11 · Berean Standard Bible
The waters covered their foes; not one of them remained.
Context
9O bá Òkun Pupa wí, ó sì gbẹ;
o sì mú wọn la ìbú já bí aginjù. 10O gbà wọ́n là kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn,
láti ọwọ́ ọ̀tá ni o ti gbà wọ́n. 11Omi ya lu àwọn ọ̀tá wọn;
bẹ́ẹ̀ ni kò sí èyí tí ó yè nínú wọn. 12Nígbà náà wọn gba ìpinnu rẹ gbọ́
wọ́n sì kọrin ìyìn rẹ. 13Ṣùgbọ́n wọn kò pẹ́ gbàgbé ohun tí o ṣe
wọn kò sí dúró gba ìmọ̀ràn rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.