Saamu 106:13
Psalms 106:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ṣùgbọ́n wọn kò pẹ́ gbàgbé ohun tí o ṣe wọn kò sí dúró gba ìmọ̀ràn rẹ.
Psalms 106:13 in English
Psalms 106:13 · Berean Standard Bible
Yet they soon forgot His works and failed to wait for His counsel.
Context
11Omi ya lu àwọn ọ̀tá wọn;
bẹ́ẹ̀ ni kò sí èyí tí ó yè nínú wọn. 12Nígbà náà wọn gba ìpinnu rẹ gbọ́
wọ́n sì kọrin ìyìn rẹ. 13Ṣùgbọ́n wọn kò pẹ́ gbàgbé ohun tí o ṣe
wọn kò sí dúró gba ìmọ̀ràn rẹ. 14Nínú aginjù ni wọ́n tí ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́,
nínú aṣálẹ̀, wọ́n dán Ọlọ́run wò. 15Nígbà náà, ó fún wọn ní ohun tí wọ́n béèrè fún
ṣùgbọ́n ó rán àìsàn búburú sí wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.