Native Bible

Psalms 105:34 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó sọ̀rọ̀, eṣú sì dé, àti kòkòrò ní àìníye,

Psalms 105:34 in English

Psalms 105:34 · Berean Standard Bible

He spoke, and the locusts came— young locusts without number.

Context

32Ó sọ òjò di yìnyín, àti ọ̀wọ́-iná ní ilẹ̀ wọn; 33Ó lu àjàrà wọn àti igi ọ̀pọ̀tọ́ wọn ó sì dá igi orílẹ̀-èdè wọn. 34Ó sọ̀rọ̀, eṣú sì dé, àti kòkòrò ní àìníye, 35wọn sì jẹ gbogbo ewé ilẹ̀ wọn, wọ́n sì jẹ èso ilẹ̀ wọn run. 36Nígbà náà, ó kọlu gbogbo àwọn ilẹ̀ wọn, ààyò gbogbo ipá wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.