Native Bible

Psalms 105:32 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó sọ òjò di yìnyín, àti ọ̀wọ́-iná ní ilẹ̀ wọn;

Psalms 105:32 in English

Psalms 105:32 · Berean Standard Bible

He gave them hail for rain, with lightning throughout their land.

Context

30Ilẹ̀ mú ọ̀pọ̀lọ́ jáde wá, èyí tí ó lọ sí ìyẹ̀wù àwọn ọba wọn. 31Ó sọ̀rọ̀, onírúurú eṣinṣin sì dìde, ó sì hu kantíkantí ní ilẹ̀ wọn 32Ó sọ òjò di yìnyín, àti ọ̀wọ́-iná ní ilẹ̀ wọn; 33Ó lu àjàrà wọn àti igi ọ̀pọ̀tọ́ wọn ó sì dá igi orílẹ̀-èdè wọn. 34Ó sọ̀rọ̀, eṣú sì dé, àti kòkòrò ní àìníye,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.