Saamu 105:35
Psalms 105:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
wọn sì jẹ gbogbo ewé ilẹ̀ wọn, wọ́n sì jẹ èso ilẹ̀ wọn run.
Psalms 105:35 in English
Psalms 105:35 · Berean Standard Bible
They devoured every plant in their land and consumed the produce of their soil.
Context
33Ó lu àjàrà wọn àti igi ọ̀pọ̀tọ́ wọn
ó sì dá igi orílẹ̀-èdè wọn. 34Ó sọ̀rọ̀, eṣú sì dé,
àti kòkòrò ní àìníye, 35wọn sì jẹ gbogbo ewé ilẹ̀ wọn,
wọ́n sì jẹ èso ilẹ̀ wọn run. 36Nígbà náà, ó kọlu gbogbo àwọn ilẹ̀ wọn,
ààyò gbogbo ipá wọn. 37Ó mú Israẹli jáde
ti òun ti fàdákà àti wúrà,
nínú ẹ̀yà rẹ̀ kò sí aláìlera kan.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.