Saamu 105:26
Psalms 105:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó rán Mose ìránṣẹ́ rẹ̀, àti Aaroni tí ó ti yàn.
Psalms 105:26 in English
Psalms 105:26 · Berean Standard Bible
He sent Moses His servant, and Aaron, whom He had chosen.
Context
24Olúwa, sì mú àwọn ọmọ rẹ̀ bí sí i
ó sì mú wọn lágbára jù
àwọn ọ̀tá wọn lọ 25Ó yí wọn lọ́kàn padà láti kórìíra àwọn ènìyàn
láti ṣe àrékérekè sí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. 26Ó rán Mose ìránṣẹ́ rẹ̀,
àti Aaroni tí ó ti yàn. 27Wọ́n ń ṣe iṣẹ́ ìyanu láàrín wọn
ó ṣe iṣẹ́ ìyanu ní Hamu. 28Ó rán òkùnkùn, o sì mú ilẹ̀ ṣú
wọn kò sì sọ̀rọ̀-òdì sí ọ̀rọ̀ rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.