Native Bible

Psalms 105:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Wọ́n ń ṣe iṣẹ́ ìyanu láàrín wọn ó ṣe iṣẹ́ ìyanu ní Hamu.

Psalms 105:27 in English

Psalms 105:27 · Berean Standard Bible

They performed His miraculous signs among them, and wonders in the land of Ham.

Context

25Ó yí wọn lọ́kàn padà láti kórìíra àwọn ènìyàn láti ṣe àrékérekè sí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. 26Ó rán Mose ìránṣẹ́ rẹ̀, àti Aaroni tí ó ti yàn. 27Wọ́n ń ṣe iṣẹ́ ìyanu láàrín wọn ó ṣe iṣẹ́ ìyanu ní Hamu. 28Ó rán òkùnkùn, o sì mú ilẹ̀ ṣú wọn kò sì sọ̀rọ̀-òdì sí ọ̀rọ̀ rẹ̀. 29Ó sọ omi wọn di ẹ̀jẹ̀, ó pa ẹja wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.