Native Bible

Psalms 105:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa, sì mú àwọn ọmọ rẹ̀ bí sí i ó sì mú wọn lágbára jù àwọn ọ̀tá wọn lọ

Psalms 105:24 in English

Psalms 105:24 · Berean Standard Bible

And the LORD made His people very fruitful, more numerous than their foes,

Context

22gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ̀, kí ó máa ṣe àkóso àwọn ọmọ-aládé kí ó sì kọ́ àwọn àgbàgbà rẹ̀ ní ọgbọ́n. 23Israẹli wá sí Ejibiti; Jakọbu sì ṣe àtìpó ní ilé Hamu. 24Olúwa, sì mú àwọn ọmọ rẹ̀ bí sí i ó sì mú wọn lágbára jù àwọn ọ̀tá wọn lọ 25Ó yí wọn lọ́kàn padà láti kórìíra àwọn ènìyàn láti ṣe àrékérekè sí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀. 26Ó rán Mose ìránṣẹ́ rẹ̀, àti Aaroni tí ó ti yàn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.