Native Bible

Psalms 105:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Israẹli wá sí Ejibiti; Jakọbu sì ṣe àtìpó ní ilé Hamu.

Psalms 105:23 in English

Psalms 105:23 · Berean Standard Bible

Then Israel entered Egypt; Jacob dwelt in the land of Ham.

Context

21Ó fi jẹ olúwa lórí ilẹ̀ rẹ̀, aláṣẹ lórí ohun gbogbo tí ó ní, 22gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ̀, kí ó máa ṣe àkóso àwọn ọmọ-aládé kí ó sì kọ́ àwọn àgbàgbà rẹ̀ ní ọgbọ́n. 23Israẹli wá sí Ejibiti; Jakọbu sì ṣe àtìpó ní ilé Hamu. 24Olúwa, sì mú àwọn ọmọ rẹ̀ bí sí i ó sì mú wọn lágbára jù àwọn ọ̀tá wọn lọ 25Ó yí wọn lọ́kàn padà láti kórìíra àwọn ènìyàn láti ṣe àrékérekè sí àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.