Saamu 102:17
Psalms 102:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Yóò dáhùn àdúrà àwọn aláìní; kì yóò sì gan ẹ̀bẹ̀ wọn.
Psalms 102:17 in English
Psalms 102:17 · Berean Standard Bible
He will turn toward the prayer of the destitute; He will not despise their prayer.
Context
15Àwọn kèfèrí yóò bẹ̀rù orúkọ Olúwa,
gbogbo ọba ayé yóò máa bẹ̀rù ògo rẹ. 16Torí tí Olúwa yóò gbé Sioni ró, yóò farahàn nínú ògo rẹ̀. 17Yóò dáhùn àdúrà àwọn aláìní;
kì yóò sì gan ẹ̀bẹ̀ wọn. 18Jẹ́ kí a kọ èyí fún ìran tí ń bọ̀,
àwọn ènìyàn tí a kò tí ì dá yóò yin Olúwa: 19“Olúwa wo ilẹ̀ láti òkè mímọ́ rẹ̀ wá
láti ọ̀run wá ni ó bojú wo ayé,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.