Native Bible

Psalms 102:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jẹ́ kí a kọ èyí fún ìran tí ń bọ̀, àwọn ènìyàn tí a kò tí ì dá yóò yin Olúwa:

Psalms 102:18 in English

Psalms 102:18 · Berean Standard Bible

Let this be written for the generation to come, so that a people not yet created may praise the LORD.

Context

16Torí tí Olúwa yóò gbé Sioni ró, yóò farahàn nínú ògo rẹ̀. 17Yóò dáhùn àdúrà àwọn aláìní; kì yóò sì gan ẹ̀bẹ̀ wọn. 18Jẹ́ kí a kọ èyí fún ìran tí ń bọ̀, àwọn ènìyàn tí a kò tí ì dá yóò yin Olúwa: 19“Olúwa wo ilẹ̀ láti òkè mímọ́ rẹ̀ wá láti ọ̀run wá ni ó bojú wo ayé, 20láti gbọ́ ìrora ará túbú, láti tú àwọn tí a yàn sí ikú sílẹ̀.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.