Native Bible

Psalms 102:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Torí tí Olúwa yóò gbé Sioni ró, yóò farahàn nínú ògo rẹ̀.

Psalms 102:16 in English

Psalms 102:16 · Berean Standard Bible

For the LORD will rebuild Zion; He has appeared in His glory.

Context

14Nítorí tí àwọn òkúta jẹ́ inú dídùn sí àwọn ìránṣẹ́ rẹ; wọ́n sì káàánú erùpẹ̀ rẹ. 15Àwọn kèfèrí yóò bẹ̀rù orúkọ Olúwa, gbogbo ọba ayé yóò máa bẹ̀rù ògo rẹ. 16Torí tí Olúwa yóò gbé Sioni ró, yóò farahàn nínú ògo rẹ̀. 17Yóò dáhùn àdúrà àwọn aláìní; kì yóò sì gan ẹ̀bẹ̀ wọn. 18Jẹ́ kí a kọ èyí fún ìran tí ń bọ̀, àwọn ènìyàn tí a kò tí ì dá yóò yin Olúwa:

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.