Òwe 8:20
Proverbs 8:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Mò ń rìn ní ọ̀nà òdodo, ní ojú ọ̀nà òtítọ́,
Proverbs 8:20 in English
Proverbs 8:20 · Berean Standard Bible
I walk in the way of righteousness, along the paths of justice,
Context
18Lọ́dọ̀ mi ni ọrọ̀ àti ọlá wà,
ọrọ̀ tí í tọ́jọ́ àti ìgbéga rere. 19Èso mi dára ju wúrà dáradára lọ;
ohun tí mò ń mú wá ju àṣàyàn fàdákà lọ. 20Mò ń rìn ní ọ̀nà òdodo,
ní ojú ọ̀nà òtítọ́, 21mò ń fi ọrọ̀ fún gbogbo àwọn tí ó fẹ́ràn mi
mo sì ń mú kí ilé ìṣúra wọn kún. 22“Èmi ni Olúwa kọ́kọ́ dá nínú iṣẹ́ rẹ̀.
Ṣáájú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ àtijọ́;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.