Native Bible

Proverbs 8:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èso mi dára ju wúrà dáradára lọ; ohun tí mò ń mú wá ju àṣàyàn fàdákà lọ.

Proverbs 8:19 in English

Proverbs 8:19 · Berean Standard Bible

My fruit is better than gold, pure gold, and my harvest surpasses choice silver.

Context

17Mo fẹ́ràn àwọn tí ó fẹ́ràn mi, àwọn tí ó sì wá mi rí mi. 18Lọ́dọ̀ mi ni ọrọ̀ àti ọlá wà, ọrọ̀ tí í tọ́jọ́ àti ìgbéga rere. 19Èso mi dára ju wúrà dáradára lọ; ohun tí mò ń mú wá ju àṣàyàn fàdákà lọ. 20Mò ń rìn ní ọ̀nà òdodo, ní ojú ọ̀nà òtítọ́, 21mò ń fi ọrọ̀ fún gbogbo àwọn tí ó fẹ́ràn mi mo sì ń mú kí ilé ìṣúra wọn kún.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.