Òwe 8:22
Proverbs 8:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Èmi ni Olúwa kọ́kọ́ dá nínú iṣẹ́ rẹ̀. Ṣáájú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ àtijọ́;
Proverbs 8:22 in English
Proverbs 8:22 · Berean Standard Bible
The LORD created me as His first course,* before His works of old.
Context
20Mò ń rìn ní ọ̀nà òdodo,
ní ojú ọ̀nà òtítọ́, 21mò ń fi ọrọ̀ fún gbogbo àwọn tí ó fẹ́ràn mi
mo sì ń mú kí ilé ìṣúra wọn kún. 22“Èmi ni Olúwa kọ́kọ́ dá nínú iṣẹ́ rẹ̀.
Ṣáájú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ àtijọ́; 23a ti yàn mí láti ayérayé,
láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, kí ayé tó bẹ̀rẹ̀. 24Nígbà tí kò tí ì sí Òkun, ni a ti bí mi,
nígbà tí kò tí ì sí ìsun tí ó ní omi nínú;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.