Òwe 7:13
Proverbs 7:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó dìímú, ó sì fẹnukò ó ní ẹnu pẹ̀lú ojú díndín ó wí pé,
Proverbs 7:13 in English
Proverbs 7:13 · Berean Standard Bible
She seizes him and kisses him; she brazenly says to him:
Context
11(Ó jẹ́ aláriwo àti alágídí,
ìdí rẹ̀ kì í jókòó nílé; 12bí ó ti ń já níhìn-ín ní ó ń já lọ́hùn ún
gbogbo orígun ni ó ti ń ba ní ibùba.) 13Ó dìímú, ó sì fẹnukò ó ní ẹnu
pẹ̀lú ojú díndín ó wí pé, 14“Mo ní ọrẹ àlàáfíà ní ilé;
lónìí ni mo san ẹ̀jẹ́ mi. 15Nítorí náà ni n o ṣe jáde wá pàdé è rẹ;
mo wá ọ káàkiri mo sì ti rí ọ!
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.