Native Bible

Proverbs 7:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

bí ó ti ń já níhìn-ín ní ó ń já lọ́hùn ún gbogbo orígun ni ó ti ń ba ní ibùba.)

Proverbs 7:12 in English

Proverbs 7:12 · Berean Standard Bible

Now in the street, now in the squares, she lurks at every corner.

Context

10Bẹ́ẹ̀ ni obìnrin kan jáde wá láti pàdé rẹ̀, ó múra bí panṣágà pẹ̀lú ètè búburú. 11(Ó jẹ́ aláriwo àti alágídí, ìdí rẹ̀ kì í jókòó nílé; 12bí ó ti ń já níhìn-ín ní ó ń já lọ́hùn ún gbogbo orígun ni ó ti ń ba ní ibùba.) 13Ó dìímú, ó sì fẹnukò ó ní ẹnu pẹ̀lú ojú díndín ó wí pé, 14“Mo ní ọrẹ àlàáfíà ní ilé; lónìí ni mo san ẹ̀jẹ́ mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.