Òwe 7:11
Proverbs 7:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
(Ó jẹ́ aláriwo àti alágídí, ìdí rẹ̀ kì í jókòó nílé;
Proverbs 7:11 in English
Proverbs 7:11 · Berean Standard Bible
She is loud and defiant; her feet do not remain at home.
Context
9Ní ìrọ̀lẹ́ bí oòrùn ṣe ń wọ̀,
bí òkùnkùn ṣe ń bo ni lára. 10Bẹ́ẹ̀ ni obìnrin kan jáde wá láti pàdé rẹ̀,
ó múra bí panṣágà pẹ̀lú ètè búburú. 11(Ó jẹ́ aláriwo àti alágídí,
ìdí rẹ̀ kì í jókòó nílé; 12bí ó ti ń já níhìn-ín ní ó ń já lọ́hùn ún
gbogbo orígun ni ó ti ń ba ní ibùba.) 13Ó dìímú, ó sì fẹnukò ó ní ẹnu
pẹ̀lú ojú díndín ó wí pé,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.