Òwe 3:8
Proverbs 3:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èyí yóò mú ìlera fún ara rẹ àti okun fún àwọn egungun rẹ.
Proverbs 3:8 in English
Proverbs 3:8 · Berean Standard Bible
This will bring healing to your body * and refreshment * to your bones.
Context
6Mọ̀ ọ́n ní gbogbo ọ̀nà rẹ
òun yóò sì máa tọ́ ipa ọ̀nà rẹ. 7Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara à rẹ
bẹ̀rù Olúwa kí o sì kórìíra ibi. 8Èyí yóò mú ìlera fún ara rẹ
àti okun fún àwọn egungun rẹ. 9Fi ọrọ̀ rẹ bọ̀wọ̀ fún Olúwa,
pẹ̀lú àkọ́so oko rẹ, 10nígbà náà ni àká rẹ yóò kún àkúnya
àgbá rẹ yóò kún àkúnwọ́sílẹ̀ fún wáìnì tuntun.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.