Native Bible

Proverbs 3:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara à rẹ bẹ̀rù Olúwa kí o sì kórìíra ibi.

Proverbs 3:7 in English

Proverbs 3:7 · Berean Standard Bible

Be not wise in your own eyes; fear the LORD and turn away from evil.

Context

5Gbẹ́kẹ̀lé Olúwa pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ má ṣe sinmi lé òye ara à rẹ. 6Mọ̀ ọ́n ní gbogbo ọ̀nà rẹ òun yóò sì máa tọ́ ipa ọ̀nà rẹ. 7Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara à rẹ bẹ̀rù Olúwa kí o sì kórìíra ibi. 8Èyí yóò mú ìlera fún ara rẹ àti okun fún àwọn egungun rẹ. 9Fi ọrọ̀ rẹ bọ̀wọ̀ fún Olúwa, pẹ̀lú àkọ́so oko rẹ,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.