Òwe 3:9
Proverbs 3:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Fi ọrọ̀ rẹ bọ̀wọ̀ fún Olúwa, pẹ̀lú àkọ́so oko rẹ,
Proverbs 3:9 in English
Proverbs 3:9 · Berean Standard Bible
Honor the LORD with your wealth and with the firstfruits of all your harvest;
Context
7Má ṣe jẹ́ ọlọ́gbọ́n lójú ara à rẹ
bẹ̀rù Olúwa kí o sì kórìíra ibi. 8Èyí yóò mú ìlera fún ara rẹ
àti okun fún àwọn egungun rẹ. 9Fi ọrọ̀ rẹ bọ̀wọ̀ fún Olúwa,
pẹ̀lú àkọ́so oko rẹ, 10nígbà náà ni àká rẹ yóò kún àkúnya
àgbá rẹ yóò kún àkúnwọ́sílẹ̀ fún wáìnì tuntun. 11Ọmọ mi, má ṣe kẹ́gàn ìbáwí Olúwa
má sì ṣe bínú nígbà tí ó bá ń bá ọ wí,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.