Native Bible

Proverbs 24:32 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsi mo sì kẹ́kọ̀ọ́ lára ohun tí mo rí;

Proverbs 24:32 in English

Proverbs 24:32 · Berean Standard Bible

I observed and took it to heart; I looked and received instruction:

Context

30Mo kọjá níbi oko ọ̀lẹ, mo kọjá níbi ọgbà àjàrà aláìgbọ́n ènìyàn; 31ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo, koríko ti gba gbogbo oko náà. 32Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsi mo sì kẹ́kọ̀ọ́ lára ohun tí mo rí; 33oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera díẹ̀ láti sinmi, 34òsì yóò sì dé bá ọ bí adigunjalè àti àìní bí olè.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.