Native Bible

Proverbs 24:31 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo, koríko ti gba gbogbo oko náà.

Proverbs 24:31 in English

Proverbs 24:31 · Berean Standard Bible

Thorns had grown up everywhere, thistles had covered the ground, and the stone wall was broken down.

Context

29Má ṣe wí pé, “Èmi yóò ṣe é fún un gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe fún mi; Èmi yóò san ohun tí ó ṣe fún mi padà fún un.” 30Mo kọjá níbi oko ọ̀lẹ, mo kọjá níbi ọgbà àjàrà aláìgbọ́n ènìyàn; 31ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo, koríko ti gba gbogbo oko náà. 32Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsi mo sì kẹ́kọ̀ọ́ lára ohun tí mo rí; 33oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera díẹ̀ láti sinmi,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.