Native Bible

Proverbs 24:33 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera díẹ̀ láti sinmi,

Proverbs 24:33 in English

Proverbs 24:33 · Berean Standard Bible

A little sleep, a little slumber, a little folding of the hands to rest,

Context

31ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo, koríko ti gba gbogbo oko náà. 32Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsi mo sì kẹ́kọ̀ọ́ lára ohun tí mo rí; 33oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera díẹ̀ láti sinmi, 34òsì yóò sì dé bá ọ bí adigunjalè àti àìní bí olè.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.